Alhaji Mukaila Lamidi fesi si oro ti Kanranjogbon ilumooka ni Sunday Adeyemo ti gbogbo eyan mo si Sunday igboho so Lori BBC Yoruba. A...
Alhaji Mukaila Lamidi fesi si oro ti Kanranjogbon ilumooka ni Sunday Adeyemo ti gbogbo eyan mo si Sunday igboho so Lori BBC Yoruba.
Alaga Park Management ti Ipinle Oyo Alh Lamidi Mukaila ti inogije re n je Auxiliary ti fesi si oro ti igboho so Lori ero ayelukara wipe ohun ko ye nipo Olori awon awako nipinle Oyo. MMK wipe aitetemole, ole Sunday igboho nmoloko.
MMK ni didalowoko iwa ibaje eyi ti Sunday Adeyemo n wu ni garage ti o wa ni Soka ni o fa gbomisi omi o too eyi o sele ni Ojo Aje ti o koja.
Ninu oro re o wipe se ti oju akata ba maa lewo, se enu Adiye Sunday Igboho lo ye ki a ti gbo.
Leni to je wipe ojoojumo lo fin daamu awon olugbe Soka. Onile o gbodo fe kan ile, awon omo Ogun re yio ti tele sibe lati gbowo omo onile. Owo ipile ile, borehole, dekini kikun ati beebee lo.
O je ki o di mimo wipe lojo aje ti o koja ni okiki kan de ba own ni ofisi wipe Sunday igboho ti fi ibon le awon olokada ati olutaja Soka kuro. Logan ni own si lo sibe lati lo petu si aawo naa. Leyi ti o si ferege nigba ti o gburo wipe owun ti nbo lona.
MMK wa ro gbogbo Omo Ipinle Oyo paapa julo olugbe inu Ibadan lati fi okan bale.
Ijoba ti o n lo lowo o fe jagidijagan ati iwa yiyan omolakeji je. O wipe ohun ti setan lati fowosopo pelu ijoba Ipinle Oyo lati gbogun ti iwa ibaje ati iwa jagidijagan.
The truth is an offence but not a sin.
ReplyDeleteKinin o kan Sunday Igboho pelu awako ipinle oyo, se o tii join Union ni?
Hmmm! Oro sunukun
ReplyDeleteWon nwa gbogbo ona lati so mmk lenu nio. Awon obayeje. Olorun tori yan mmk koni pada leyin re.
ReplyDeleteeyin meje ji agbalagba ni yin ema je koba jee oooooo
ReplyDeleteeyin meje ji agbalagba ni yin ema je koba jee oooooo
ReplyDeleteEmio ba be ijoba ipinle oyo kotete dasi oro yio hummm tori ibi erin meji bati ja koriko ibe kotun gberi mon ooo Aburu koni sele siwa ooo
ReplyDeleteO ma see Lara alamodi o,MMK o ka ju e bi awo oba ka oju ilu yiya lo man ya MMK o ka jue
ReplyDeleteKnni ti Sunday igbohoo pelu oro Park manager you better face your business
ReplyDeleteA fe wahala ni ipinle Oyo tiwa
ReplyDeleteAti igun kini Ati igun keji ejo emada omi alafia ipinle Oyo run esemedo
ReplyDeleteIn fact booda Sunday disappoint mi ajijagbara nimomowon si now, eniti kofe iyanje tosin se aanu, tobaje otito ni ounti mmk soyi, kiwon ma sebe moo, eni aponle niwon
ReplyDeleteGomina ipinle oyo ni emi fe gbe ni yanju ki won fi ewe Omo mo Sunday igboho leti ko ma bada wahala Sile o
ReplyDeleteGomina ipinle oyo ni emi fe gbe ni yanju ki won fi ewe Omo mo Sunday igboho leti ko ma bada wahala Sile o
ReplyDeleteHumm,oro sunukun Oju sunukun la n fi wo ,eyin agba gba e pe igun ikinni pelu igun orji ke si pari awor yii fawon mejeji ki ife le wa Kari ilu ibadan
ReplyDeleteHumm,oro sunukun Oju sunukun la n fi wo ,eyin agba gba e pe igun ikinni pelu igun orji ke si pari awor yii fawon mejeji ki ife le wa Kari ilu ibadan
ReplyDeleteOlorun Oba kokukuni gbafun Awon obayeje lati baaaa ijoba GSM Ati MMK Je Omi titun igba otun
ReplyDeleteKolorun maa so wa lowo eni ibi
ReplyDelete