SOKA: Mukaila fesi si oro ti Karanjogbon ilumoka Sunday Igboho so lori BBC yoruba

SHARE THIS:

Alhaji Mukaila Lamidi fesi si oro ti Kanranjogbon ilumooka ni Sunday Adeyemo ti gbogbo eyan mo si Sunday igboho so Lori BBC Yoruba. Alaga Pa...

Alhaji Mukaila Lamidi fesi si oro ti Kanranjogbon ilumooka ni Sunday Adeyemo ti gbogbo eyan mo si Sunday igboho so Lori BBC Yoruba.

Alaga Park Management ti Ipinle Oyo Alh Lamidi Mukaila ti inogije re n je Auxiliary ti fesi si oro ti igboho so Lori ero ayelukara wipe ohun ko ye nipo Olori awon awako nipinle Oyo. MMK wipe aitetemole, ole Sunday igboho nmoloko. 

MMK ni didalowoko iwa ibaje eyi ti Sunday Adeyemo n wu ni garage ti o wa ni Soka ni o fa gbomisi omi o too eyi o sele ni Ojo Aje ti o koja. 

Ninu oro re o wipe se ti oju akata ba maa lewo, se enu Adiye Sunday Igboho lo ye ki a ti gbo. 
Leni to je wipe ojoojumo lo fin daamu awon olugbe Soka. Onile o gbodo fe kan ile, awon omo Ogun re yio ti tele sibe lati gbowo omo onile. Owo ipile ile, borehole, dekini kikun ati beebee lo.

O je ki o di mimo wipe lojo aje ti o koja ni okiki kan de ba own ni ofisi wipe Sunday igboho ti fi ibon le awon olokada ati olutaja Soka kuro. Logan ni own si lo sibe lati lo petu si aawo naa. Leyi ti o si ferege nigba ti o gburo wipe owun ti nbo lona. 

MMK wa ro gbogbo Omo Ipinle Oyo paapa julo olugbe inu Ibadan lati fi okan bale.
 Ijoba ti o n lo lowo o fe jagidijagan ati iwa yiyan omolakeji je. O wipe ohun ti setan lati fowosopo pelu ijoba Ipinle Oyo lati gbogun ti iwa ibaje ati iwa jagidijagan.

COMMENTS

BLOGGER: 17
  1. The truth is an offence but not a sin.
    Kinin o kan Sunday Igboho pelu awako ipinle oyo, se o tii join Union ni?

    ReplyDelete
  2. Won nwa gbogbo ona lati so mmk lenu nio. Awon obayeje. Olorun tori yan mmk koni pada leyin re.

    ReplyDelete
  3. eyin meje ji agbalagba ni yin ema je koba jee oooooo

    ReplyDelete
  4. eyin meje ji agbalagba ni yin ema je koba jee oooooo

    ReplyDelete
  5. Emio ba be ijoba ipinle oyo kotete dasi oro yio hummm tori ibi erin meji bati ja koriko ibe kotun gberi mon ooo Aburu koni sele siwa ooo

    ReplyDelete
  6. O ma see Lara alamodi o,MMK o ka ju e bi awo oba ka oju ilu yiya lo man ya MMK o ka jue

    ReplyDelete
  7. Knni ti Sunday igbohoo pelu oro Park manager you better face your business

    ReplyDelete
  8. A fe wahala ni ipinle Oyo tiwa

    ReplyDelete
  9. Ati igun kini Ati igun keji ejo emada omi alafia ipinle Oyo run esemedo

    ReplyDelete
  10. In fact booda Sunday disappoint mi ajijagbara nimomowon si now, eniti kofe iyanje tosin se aanu, tobaje otito ni ounti mmk soyi, kiwon ma sebe moo, eni aponle niwon

    ReplyDelete
  11. Gomina ipinle oyo ni emi fe gbe ni yanju ki won fi ewe Omo mo Sunday igboho leti ko ma bada wahala Sile o

    ReplyDelete
  12. Gomina ipinle oyo ni emi fe gbe ni yanju ki won fi ewe Omo mo Sunday igboho leti ko ma bada wahala Sile o

    ReplyDelete
  13. Humm,oro sunukun Oju sunukun la n fi wo ,eyin agba gba e pe igun ikinni pelu igun orji ke si pari awor yii fawon mejeji ki ife le wa Kari ilu ibadan

    ReplyDelete
  14. Humm,oro sunukun Oju sunukun la n fi wo ,eyin agba gba e pe igun ikinni pelu igun orji ke si pari awor yii fawon mejeji ki ife le wa Kari ilu ibadan

    ReplyDelete
  15. Olorun Oba kokukuni gbafun Awon obayeje lati baaaa ijoba GSM Ati MMK Je Omi titun igba otun

    ReplyDelete
  16. Kolorun maa so wa lowo eni ibi

    ReplyDelete

Name

celebrity,2,crime,52,Education,96,Entertainment,20,Eye Witness,6,gist,2,gossip,2,Health,10,Lifestyle,32,new,6,newa,2,News,1004,Opinion,4,Politics,342,religion,2,sport,6,Sports,2,Tech news,2,
ltr
item
Mouthpiece NGR: SOKA: Mukaila fesi si oro ti Karanjogbon ilumoka Sunday Igboho so lori BBC yoruba
SOKA: Mukaila fesi si oro ti Karanjogbon ilumoka Sunday Igboho so lori BBC yoruba
https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEipB6xUUu6bqJOVSFHihyphenhyphend8Wg6klmrEWd3RAGhMW1pcsIENIBVL_CaNGAljfc6Cc5tYO4QtTGvttREMqf0g9ObGah3_Wik7bfr3gsKyVBxLWV1kQpuumNtKq54Ic_PnXM_Fr9P24SQ1QKg/s320/AAC6A1A8-F565-4CFD-B37F-50C27F63C44C.jpeg
https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEipB6xUUu6bqJOVSFHihyphenhyphend8Wg6klmrEWd3RAGhMW1pcsIENIBVL_CaNGAljfc6Cc5tYO4QtTGvttREMqf0g9ObGah3_Wik7bfr3gsKyVBxLWV1kQpuumNtKq54Ic_PnXM_Fr9P24SQ1QKg/s72-c/AAC6A1A8-F565-4CFD-B37F-50C27F63C44C.jpeg
Mouthpiece NGR
https://newtechng.blogspot.com/2020/04/soka-mukaila-fesi-si-oro-ti-karanjogbon_11.html
https://newtechng.blogspot.com/
http://newtechng.blogspot.com/
http://newtechng.blogspot.com/2020/04/soka-mukaila-fesi-si-oro-ti-karanjogbon_11.html
true
9158385905510168786
UTF-8
Loaded All Posts Not found any posts VIEW ALL Read more Reply Cancel reply Delete By Home PAGES POSTS View All RECOMMENDED FOR YOU LABEL ARCHIVE SEARCH ALL POSTS Not found any post match with your request Back Home Sunday Monday Tuesday Wednesday Thursday Friday Saturday Sun Mon Tue Wed Thu Fri Sat January February March April May June July August September October November December Jan Feb Mar Apr May Jun Jul Aug Sep Oct Nov Dec just now 1 minute ago $$1$$ minutes ago 1 hour ago $$1$$ hours ago Yesterday $$1$$ days ago $$1$$ weeks ago more than 5 weeks ago Followers Follow THIS PREMIUM CONTENT IS LOCKED STEP 1: Share. STEP 2: Click the link you shared to unlock Copy All Code Select All Code All codes were copied to your clipboard Can not copy the codes / texts, please press [CTRL]+[C] (or CMD+C with Mac) to copy